Jump to content

Descent (2017 film)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Descent jẹ́ fíìmù orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí Bridget Phathudi kọ, Abdulfatai Awal tí Nwankwo Chibuzor ṣe àti oludari rẹ̀ ni Abdulfatai Awal. Fíìmù naa ṣe afihan ni sinima ni Oṣu kejila ọjọ kini ọdun 2017. Fíìmù naa n se ṣapejuwe àwọn ọran tí o jọmọ idile, ogun oloro, ifẹ, ẹ̀san àti ọpọlọpọ nkan die sii. Descent ti gba Aami Idanimọ fun Aworan Tirela Kariaye tí o dara julọ àti ni ọdun tí o gba Aami Eye fíìmù Pataki (SMA) ni Orilẹ-ede Gambia.

Fíìmù naa n sọ ìtàn kan tí àwọn ọba abẹ́lẹ̀ méjì tí ojúkòkòrò àti òùngbẹ fún agbára àti ẹ̀san mú wọn wá sínú ìpalára fún ẹbí ara wọn. Fíìmù naa jẹ apapo ere àti iṣe bi ifura àti awọn ẹdun le fi àwọn oluwo re si eti kan ati ni omije. Fíìmù naa ṣe afihan itan-akọọlẹ otitọ tí Afirika ti idile, iwa-ipa, igbẹkẹle, ojukokoro àti agbara.

Diẹ ninu àwọn oṣere pataki ninu fiimu naa pẹlu;

  • Zack Orji bi Kalu Achebe
  • Matt Stern bi Andrew Morgan
  • Palesa Madisakwane
  • JT Medupe
  • Tayo Faniran
  • Benedikt Sebastian