Ebenezer Andrews

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ebenezer Andrews ni a bini ọjọ mọkan lèèlogun, óṣu May ni ọdun 2000 jẹ elere badminton ti ilẹ ghana. Ni óṣu April, ọdun 2019 elere naa jẹ ọkan lara team ilẹ ghana to gba ami ọla ti idẹ ni idije ti gbogbo ilẹ afirica to waye ni Port Harcourt, Naigiria[1][2][3][4][5].

Igbèsi Ayè Arakunrin naa[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Andrews wa lati Winneba ni ilẹ ghana to si jẹ akẹẹkọ ti ilè iwè giga to da lori ẹkọ ni Winneba[6][7][8].

Iṣẹ ati Àṣèyọri[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Andrews kopa ninu idije Badminton U-19 ti Junior gbogbo ilẹ afirica to waye ni Algeria ni ọdun 2013[9]. Elere na kopa ninu ere ẹlẹkẹwa ti gbogbo ilẹ afirica ni ilè iwè giga ti Kenyatta ni Nairobi, ilẹ Kenya[10]. Ni ọdun 2018, Andrews ati Akẹgbẹ rẹ Daniel Doe gba gold ninu ere ti commonwealth to waye ni ilẹ Australia ni doubles finals[11].

Itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. https://badmintonstatistics.net/Player?playerid=132020714
  2. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2023-03-01. Retrieved 2023-03-09. 
  3. https://www.flashscore.com/player/andrews-ebenezer/W0XTdpV3/
  4. https://bwfworldtourfinals.bwfbadminton.com/player/55927/ebenezer-andrews
  5. https://citisportsonline.com/2019/08/26/african-games-2019-day-7-ghanaian-athletes-succeed-in-heats/
  6. https://www.liquidsportsghana.com/uew-clinches-historic-3rd-place-at-african-uni-games/
  7. https://glitzsport.com/team/5229-2-2/
  8. https://allafrica.com/stories/202206160542.html
  9. https://www.myjoyonline.com/ghana-to-compete-in-africa-badminton-junior-championships/
  10. https://badmintonafrica.com/10th-all-africa-university-games-2022/
  11. https://ghanaguardian.com/ghana-badminton-team-sweeps-victory-19-championship