Jump to content

Edna Adan Ismail

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Edna Adan Ismail
Ọjọ́ìbí8 September 1937 (1937-09-08) (ọmọ ọdún 87)
Hargeisa, British Somaliland
Ẹ̀kọ́Borough Polytechnic, currently London South Bank University
Iṣẹ́Activist
Gbajúmọ̀ fúnActivist for the abolition of female genital mutilation (FGM)
Office8th Minister of Foreign Affairs
PredecessorMohammad Saed Gees
SuccessorAbdilahi Mohamed Dualeh
Olólùfẹ́Mohamed Haji Ibrahim Egal
AwardsTempleton Prize (2023)
Signature

Edna Adan Ismail (tí wọ́n bí ní born 8 September 1937) jẹ́ agbẹ̀bí, ajàfẹ́tọ̀ọ́mọnìyàn, ó sí tún jẹ́ obìnrin àkọ́kọ́ tó jẹ́ Mínísítà fún ọ̀rọ̀ ilẹ̀ òkèrè, fún orílẹ̀-èdè Somalia[1] láti ọdún 2003 wọ 2006. Òun sì ni ààrẹ ẹgbẹ́ Victims of Torture.[2]

Ìbẹ̀rẹ̀pẹlpẹ̀ ayé rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Ismail pẹ̀lú ẹranko tó fi ń ṣeré ní ọdún 1968.

Ìlú Hargeisa ni wọ́n bí Ismail sí, ní 8 September 1937,[3] ó sì jẹ́ ọmọ oníṣègùn kan.[4] Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ márùn-ún tí ìyá rè bí, àmọ́ méjì kú nínú wọn lásìkò ìbí wọn.[5][6]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Gettleman, Jeffrey (2 June 2009). "No Winner Seen in Somalia's Battle With Chaos". The New York Times. https://www.nytimes.com/2009/06/02/world/africa/02somalia.html. 
  2. Topping, Alexandra (23 June 2014). "Somaliland's leading lady for women's rights: 'It is time for men to step up'". The Guardian. https://www.theguardian.com/world/2014/jun/23/somaliland-womens-rights-gender-violence. 
  3. Skaine, Rosemary (2008). Women Political Leaders in Africa. McFarlane. pp. 54. ISBN 9780786432998. 
  4. "125th Anniversary - Get Involved - My Cardiff". Cf.ac.uk. Archived from the original on 13 May 2014. Retrieved 10 December 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. "Why giving birth in the U.S. is surprisingly deadly". National Geographic. 2018-12-13. https://www.nationalgeographic.com/magazine/2019/01/giving-birth-in-united-states-suprisingly-deadly/. 
  6. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :0