Jump to content

Eewo orisa to je mo iwa mimo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Èèwò ni ohun àìgbodò se, ìyen ìwà èérí tí òrìsà kórìíra. Àpeere

Obàtálá lòdì sí ìdòtí tàbí nnkan ègbin, ìwà eke, ìwà àìsòdodo, àti òdàlè.

Sàngó kórìíra ìwà olè. Àrá ni ó n sán pa olè,tí yóò sì gbé ohun tó bá jí le ní àyà.

Ògún lòdì sí ìwà iró-pípa, èké-síse, èrú-síse àti ilè-dídà. Èrèdìí tí wón fi n fi àmì Ògún se ìbúra ní ilé Ejó.

Òrìsà onínú funfun ni Òsun. Ó lòdì sí ìwà èké tàbí ìwà òdàlè. Eni tí inú rè kò bá mó kò gbodò dé ìdí òrìsà Òsun.