Efioanwan Ekpo
Ìrísí
Medal record | |||
---|---|---|---|
Women's Football | |||
Adíje fún Nàìjíríà | |||
African Championships | |||
Wúrà | 2006 Women's African Football Championship | 2006 Nigeria |
Efioanwan Ekpo jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 25, óṣu january ni ọdun 1984. Agbabọọlu naa jẹ ọkan lara ọmọ ẹgbẹ awọn obinrin apapọ lori bọọlu[1][2][3].
Aṣeyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Ekpo kopa ninu Cup agabye, olympic ati ere idije ilẹ afirica[4].