Egboogi Lumefantrine
Ìrísí
Lumefantrine (tabi benflumetol ) jẹ oogun egboogi-ibà . Lilo re gbodo je pelu artemether nikan. Nigba mii, a maa n se apejuwe re gege bii "akole apapo artemether". [1]
Lumenfantrine maa n duro pe ninu ara ju artemether lo ati pe eyi je ki a ro wipe o maa n se akotan kokoro aifojuri afaisan ti o ba seku sinu ago ara leyin itoju pelu apapo egboogi mejeeji. [2]
Awọn itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Successful co-artemether (artemether-lumefantrine) clearance of falciparum malaria in a patient with severe cholera in Mozambique". Travel Medicine and Infectious Disease 1 (3): 177–9. 2003. doi:10.1016/j.tmaid.2003.09.002. PMID 17291911.
- ↑ "Clinical Pharmacokinetics and Pharmacodynamics of Artemether-Lumefantrine". Clinical Pharmacokinetics 37 (2): 105–125. 1999. doi:10.2165/00003088-199937020-00002. PMID 10496300.