Eku

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Mus musculus
Eku ilé

Eku

Orisii meji lo wa, dudu ati pupa resuresu (brown). Awon eku maa n gun ni iwon insi merindinlogun ninu eyi ti insi mejo re maa n je iru. Won maa n ba nnkan je pupo ni pataki awon ti o dudu. Ni laboretiri, won maa n sin awon eku funfun kan ti won fi maa n se iwadii.