Agbèègbè ìdìbò ti Paddington (Queensland)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Agbèègbè ìdìbò ti Paddington jẹ́ tí àwọn tí ó lẹ̀tọ́ làti dìbò fún aṣojú ilé ìgbìmọ̀ aṣofin ti ìpínlẹ̀ Queensland, Australia.[1]

Ìtàn[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n dá Paddington sílẹ̀ ní ọdún 1911 lẹ́yìn àtúnpín ìlú, tí o sẹlẹ̀ ní ọdún 1912 nínú ìdìbò ìpínlẹ̀, agbèègbè ìdìbò yí wà títí dì ọdún 1932 ní àkókò ìdìbò ìpínlẹ̀.[1] Orisun awon agbegbe re je ni Brisbane North  èyí tí o parun nínú ìdìbò 1912.[1]

Nígbàtí Paddington parun ní ọdún 1932, àwọn agbègbè rẹ̀ dàpọ̀ mọ́ agbèègbè Brisbane ati Baroona.[1]

Àwọn aṣojú[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn enìyàn wọ̀nyí ní wón ìdìbò yàn gẹ́gẹ́ bí aṣojú Paddinton :[1][2]

Aṣojú Ẹgbẹ́ òṣèlú Ìgbà
John Fihelly Labor 27 Apr 1912 –   7 Feb 1922
Alfred James Jones Labor 18 Mar 1922 – 11 Jun 1932

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 1.2 1.3 1.4 "Representatives of Queensland State Electorates 1860 - 2012" (PDF). Queensland Parliament. Retrieved 31 January 2014. 
  2. "Alphabetical Register of Members of the Legislative Assembly 1860-2012 and of the Legislative Council 1860-1922" (PDF). Queensland Parliament. Retrieved 31 January 2014.