Emotan

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Emotan (15th century) jẹ́ obìnrin olọ́jà tí ó ná Ọjà Oba ní ayé àtijó ní Benin nígbà ìṣàkóso Oba Uwaifiokun àti Omoba Ogun, ẹni tí ó sọ ara rẹ̀ ní "Oba Ewuare the Great" lẹ́yìn tí ó di Oba of Benin.[1][2][3] Òun ni ó bẹ̀rẹ̀ day care centreÌlú Benin; Ìtàn àtenudẹ́nu sọ wípé ó ran Oba Ewuare lọ́wọ́ ní gbígba ìjọba Benin lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún tí ó ti wà níta ìlú.[4]

Ìgbé ayé rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Emotan (orúko àbísọ rẹ̀ ni Uwaraye), ní Eyaen láàrin ọdún 1380 sí 1400.[5] Lẹ́yìn ìgbà tí ọkọ rẹ̀ kú, ó kó abà kan láti tọjú àwọn ọmọ rẹ̀.[6]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. S. B. Omoregie (1972). Emotan and the Kings of Benin. Longman Group (Far East), Limited. ISBN 978-0-582-60925-9. https://books.google.com/books?id=zusJAQAAIAAJ. 
  2. Kola Onadipe (1980). Footprints on the Niger. National Press. p. 28. ISBN 9789781780066. https://books.google.com/books?id=8TgJAQAAIAAJ&q=emotan+of+benin. 
  3. Christy Akenzua (1997). Historical tales from ancient Benin. 2. July Seventeenth Co. (Indiana University). p. 40. ISBN 978-9-7831-74139. https://books.google.com/books?id=mrrfAAAAMAAJ&q=emotan+of+benin. 
  4. Trevor Schoonmaker (4 July 2003). Fela: From West Africa to West Broadway. Palgrave Macmillan. pp. 1–. ISBN 978-1-4039-6210-2. https://archive.org/details/felafromwestafri00newy. 
  5. Irene Isoken Salami (2001). Emotan (a Benin Heroine). Mazlink Nigeria Limited. ISBN 978-978-35644-3-5. https://books.google.com/books?id=W9XyAAAAMAAJ. 
  6. "MEET OBA EWUARE THE GREAT : ONE OF THE WORLD'S MOST ILLUSTRIOUS ANCIENT KINGS". The New Black Magazine. 21 December 2009. Archived from the original on 19 September 2015. https://web.archive.org/web/20150919070821/http://www.thenewblackmagazine.com/view.aspx?index=2196. Retrieved 31 August 2015.