Empress Njamah

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Empress Njamah
Ọjọ́ìbíNovember 16 [1]
Iṣẹ́Actor

Empress Njamah jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[2][3] Ní ọdún 2012, wọ́n yàán fún àmì ẹ̀yẹ ẹ̀yẹ Best supporting actress láti ọ̀dọ̀ Africa Movie Academy Award.

Ìgbésí ayé rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn òbí Njamah jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti Cameroon. Ó gboyè jáde láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Olabisi Onabanjo University nínú ìmọ̀ èdè gẹ̀ẹ́sì. Ó jẹ́ olólùfẹ́ fún olórin, Timaya tẹ́lẹ̀[4][5]. Ó bẹ̀rẹ̀ eré ṣíṣe ní ọdún 1995. Ó dá ẹgbẹ́ House of Empress kalẹ̀ láti má ṣe ìtọ́jú fún àwọn ọmọdé.[6][7]

Àṣàyàn àwọn eré tí ó tí ṣe[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọdún Àkọ́lé eré Ipa tí ó kó
2000 Girls Hostel Tunica
2004 Missing Angel
2006 Liberian Girl

Àwọn ìtọ́kàsi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]