Jump to content

Endangered languages in Nigeria

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

èdè ìlú Nàìjíríà tí owá ni ijamba láti parunMọ́kàndínlọ́gbọ̀n nínú àwọn èdè kékèké ilẹ Nàìjíríà ni ọ ti parun, mokandinlogbon omin ni o ti wa ni bèbè lati parun. Mẹ́ta nínú àwọn èdè agba ni Nàìjíríà - èdè Yorùbá, èdè Ìgbò, ati ede Itshekiri ni àwọn náà ti wa ninú ewu láti parun gẹ́gẹ́ bíi ìwádí tí awọn United Nations Educational, Scientific, and Cultural Organisation (UNESCO) ti ṣe àti ọrọ tí awọn olùkọ́ èdè àti onimọ oríṣiríṣi èdè ti sọ. Ni Ọdún 2006, Ẹgbẹ UNESCO so asotẹlẹ wipe ede Igbo, eyi ti awọn ti ówà ni ìyá guusu-iwoorun ile Naijiria nsọ, ti awọn ti wọn sile sọ èdè náà je bíi millionu ogun, le di iparun bíi àádọta odun siwajusi. Ni ọdún 2017, Alagba Dahunsi Akinyemi, olukọ ede ati onkọwe iwe Yoruba ko gbọdọ ku, so wipe ede Yoruba le ku ki a to ri ogun ọdún lọjọwaju. Alagba Dahunsi tara wipe awọn ọmọ Yorùbá ìsìn yìí kò le sọ ' mo fe jeun' ni ede iya won. Iwadi kan ti Oti ṣe ní ọdún 2014 fihan wipe ni ọdún àádọta ni ojo iwaju, ede ishekiri yóó ti di ohun igbagbe, awọn ẹgbẹ àpapọ awọn onimọ ede oríṣiríṣi náà sọ wipe ti a ko ba gbe ìgbésẹ láti má sọ àwọn èdè yìí pada, bíi èdè àádọta ninu awon ede kekeke yìí ni yóò ti di igbagbe ni ojo iwaju.