Erékùṣù Newfoundland
Sobriquet: Terra Nova | |
---|---|
Jẹ́ọ́gráfì | |
Ibùdó | Atlantic Ocean |
Àwọn ojú-afọ̀nàhàn | 49°N 56°W / 49°N 56°W |
Ààlà | 111,390 km2 (43,008 sq mi) |
Ipò ààlà | 16th |
Etíodò | 9,656 km (6,000 mi) |
Ibí tógajùlọ | 814 m (2,671 ft) |
Orí ilẹ̀ tógajùlọ̀ | The Cabox |
Orílẹ̀-èdè | |
Province | Newfoundland and Labrador |
Ìlú tótóbijùlọ | St. John's (pop. 100,646) |
Demographics | |
Ìkún | 479,105[1] (as of 2006) |
Ìsúnmọ́ra ìkún | 4.30 /km2 (11.14 /sq mi) |
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn | English, Irish, Some Scottish and French |
Ìfitọ́nilétí míràn | |
Additional Information Longest River:Exploits River
Newfoundland Red Ensign Civil ensign of the province and Dominion of Newfoundland (1907-1965) |
Erékùṣù Newfoundland (pípè /ˈnjuːfən(d)lænd/ ( listen); Faransé: Terre-Neuve, Irish: Talamh an Éisc) jẹ́ erékùṣù ti orile-ede Kanada tó wà ní wa ni 15 kilometres (9.3 mi) lati ẹ̀bá odó ìlà Oòrùn Àríwá Amẹ́ríkà, àti ibi tó kún jùlọ ní ni ìgbèríko Kanada tí Newfoundland àti Labrador wà. Orúkọ ọ́ṣìṣẹ́ ìgbèríko ọ̀hún tẹ́lẹ ni "Labrado" kí wọ́n tó yi padà sí "Newfoundland àti Labrado" ní ọdún 2001.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "2006 Statistics Canada National Census". Statistics Canada. 2009-07-28.
- ↑ "Atlas of Canada - Rivers". Natural Resources Canada. 2004-10-26. Archived from the original on 2012-03-29. Retrieved 2007-04-19.