Erykah Badu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Erica Abi Wright)
Erykah Badu
Background information
Orúkọ àbísọErica Abi Wright
Ọjọ́ìbíOṣù Kejì 26, 1971 (1971-02-26) (ọmọ ọdún 53)
Dallas, Texas, U.S.
Occupation(s)
  • Singer
  • songwriter
  • record producer
  • actress
Years active1994–present
Websiteerykah-badu.com
Musical career
Irú orin
InstrumentsVocals
Labels
Associated acts

Erica Abi Wright (ojoibi 26 Oṣù Kejì, 1971),[1] to gbajumo pelu oruko ori-itage Erykah Badu (pronounced /ˈɛrɨkə bɑːˈduː/), je omo orile-ede Amerika akorin, atokun awo-orin ati osere. Ise-owo re po mo lati R&B, hip hop ati jazz.[1] O kopa gidigidi ninu igbooro iru orin neo soul, ati iru ona toyato to fi n korin ati ona oge re. O je mimo gege bi "Iyafin Akoko Neo-Soul" ("First Lady of Neo-Soul") tabi "Ayaba Neo-Soul" (the "Queen of Neo Soul".

Awon awo-orin[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Baduizm (1997)
  • Live (1997)
  • Mama's Gun (2000)
  • Worldwide Underground (2003)
  • New Amerykah Part One (4th World War) (2008)
  • New Amerykah Part Two (Return of the Ankh) (2010)



Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 Bush, John. "Erykah Badu > Biography". Allmusic. Retrieved 2008-12-18.