Erìgì
Ìrísí
Erìgì | |
---|---|
Cross-section of a tooth with gums labeled | |
Details | |
Identifiers | |
Latin | Gingiva |
TA | A05.1.01.108 A03.1.03.003 A03.1.03.004 |
FMA | 59762 |
Anatomical terminology |
Erìgì tàbíEègìni jẹ́ àkójọpọ̀ iṣan tí ó wà lórí eegun tó gbé ẹnu dúró tí ó sì so pọ̀ mọ́ agbarí nínú làá ẹnu lọ́ùún. Ìṣòro kí ṣòro tó bá ń dojú ké erìgì yálà látara àásán, àrùn tàbí kòkò búburú lè ṣe àkóbá, kí ó sì mú kí ènìyàn tàbí ohun ẹlẹ́mìí tó bá ní eyín ó di aláìlera . [1][2]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Gum disease opens up the body to a host of infections April 6, 2016 Science News
- ↑ "Gum (Periodontal) Disease Causes, Symptoms, Diagnosis, Treatment". National Institute of Dental and Craniofacial Research. Retrieved 2020-01-06.