Ẹnu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Ẹnu
Illu01 head neck.jpg
Head and neck
Close up man lips.jpg
Photo outside the human mouth
Details
Latinos, cavitas oralis
Anatomical terminology

Nínú ìmọ̀ ẹ̀yà ara ènìyàn, ẹnu ni ẹ̀yà ara àkọ́kọ́ tí ó kángun sí ọ̀fun tí ohun jíjẹ àti mímu ń gbà kọjá, tí ó sì ń pèsè itọ́ fún ìrọ̀rùn ahọ́n kí ọ̀rọ̀ ó lè já geere. [1] Gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yà ara ìfọ̀, ẹnu ní ń agbára pèsè àti láti gba itọ́ dúró pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ epithelium tí ó wà nínú ẹnu. Lára iṣẹ́ rẹ̀, láti ẹnu ni iṣẹ́ dídà óúnjẹ ti bẹ̀rẹ̀. Bẹ́ẹ̀, ó tún ń ṣiṣẹ́ ìfọ̀, ọ̀rọ̀ sísọ tàbí ìbánisọ̀rọ̀

Ìpínsísọ̀rí ẹnu[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A lè pín ẹnu sí oríṣi ọ̀nà méjì, àkọ́kọ́ ni àbáwọlé ẹnu tí wọ́n ń pè ní (vestibule) àti ọ̀fun.

Ìrísí rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ẹnu sábà ma ń yọ̀ tàbí tutù nígbà gbogbo pẹ̀lú omi ẹnu tí a mọ̀ sí itọ́. Inú ẹnu ni eyín ń gbé nígbà tí ètè sì jẹ́ ilẹ̀kùn àbáwọlé sí ẹnu àti gbogbo ẹ̀yà ara inú tó kù pátá.

Àwọn Ìtọ́ka sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Maton, Anthea; Jean Hopkins; Charles William McLaughlin; Susan Johnson; Maryanna Quon Warner; David LaHart; Jill D. Wright (1993). Human Biology and Health. Englewood Cliffs, New Jersey, USA: Prentice Hall. ISBN 0-13-981176-1. https://archive.org/details/humanbiologyheal00scho.