Itọ́
Ìrísí
Itọ́ ni omi ara tí ó ń sun láti ibùsun kan nínú ẹnu yálà lára ènìyàn tàbí ẹranko. Lára ènìyàn, itọ́ tí ó ń sun tó ìdá 99.5 omi pẹ̀lú (electrolytes), kẹ̀lẹ̀bẹ̀, ẹ̀jẹ̀ funfun, epithelial cells níbi tí DNA ti ma ń sun jáde.[1] [2]
Iṣẹ́ tí itọ́ ń ṣe
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Itọ́ ma ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí ìbomirin ẹnu, rínrin óúnjẹ ó sì tún ma ń ṣiṣẹ́ ìgbémì, tí ó sì tún ń ìrọ̀rùn ìgbé ọ̀rọ̀ jáde kí ẹnu ó má ba gbẹ.[3] [4] [5]
Àwọn Ìtọ́ka sí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Àdàkọ:GeorgiaPhysiology
- ↑ Fejerskov, O.; Kidd, E. (2007). Dental Caries: The Disease and Its Clinical Management (2nd ed.). Wiley-Blackwell. ISBN 978-1-4051-3889-5.
- ↑ Edgar, M.; Dawes, C.; O'Mullane, D. (2004). Saliva and Oral Health (3 ed.). British Dental Association. ISBN 978-0-904588-87-3.
- ↑ Marcone, Massimo F. (2005). "Characterization of the edible bird's nest the "Caviar of the East"". Food Research International 38 (10): 1125–1134. doi:10.1016/j.foodres.2005.02.008.
- ↑ "Insect-produced silk" (PDF). Archived from the original (PDF) on 2017-01-31. Retrieved 2020-04-19.