Ìbánisọ̀rọ̀

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Ìbánisọ̀rọ̀ (láti inú èdè Látìnì :communicare,[1] tí ó túmọ̀ sí (ṣíṣalábàápín) jẹ́ ìgbésẹ̀ gbígbé is the act of conveying ìtumọ́ ọ̀rọ̀ láti ọ̀dọ̀ ẹnìkan sí ẹlòmíràn fún ìgbọ́ra-ẹni yé, yálà nípa lílo òfin tí a fiblọ́ọ́lẹ̀ nípa àmì tàbí ìṣesí tí gbogbo wa fọ́wọ́ sí. Àwọn ìgbésẹ̀ tó ṣe kókó nínú ìlànà ìbánisọ̀rọ̀ ni:[2]

 1. Kẹ́ṣẹ́ tàbí ìdí tí ìbánisọ̀rọ̀ fi wáyé.
 2. Iṣẹ́ tí a fẹ́ fi ìbánisọ̀rọ̀ yí rán jáde sí olùgbọ́ wa.
 3. Kókó tí a fẹ́ fi múlẹ̀ inú iṣẹ́ tí a rán jáde.
 4. Bí a ṣe ránṣẹ́ náà jáde tàbí ọ̀nà tí a gbà gbé iṣẹ́ náà léde.
 5. Ariwo. Èyí ma ń mú ìdíwọ́ wá nínú ìgbésẹ̀ ìbára-ẹni sọ̀rọ̀, tí kìí sì jẹ́ kí á gbọ́ ara ẹni é bí a bá ń sọ̀rọ̀ lọ. Ariwo yí lè jẹ́ ìmọ̀ọ́mọ̀ ṣe tàbí àìmọ̀ọ́mọ̀ ṣe.[3]
 6. Àgbékalẹ̀ iṣẹ́ tí a fẹ́ rán sí olùgbọ́ wa tí yóò fi gbọ́nwa yé yéké-yéké
 7. Àgbọ́yé iṣẹ́ tí olùfiránṣẹ́ fi ránṣẹ́ síwa lásìkò ìbánisọ̀rọ̀.
 8. Ìtumọ̀: bí a ṣe fún èyíkéyí iṣẹ́ tí agbọ́ àti bí ó ṣe yé wa sí ni yóò dá lórí irúfẹ́ ìtumọ́ ti a lè fún iṣẹ́ gbọ́ náà.

Àwọn Ìtọ́ka sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 1. "What is Communication? Verbal, Non-Verbal & Written". SkillsYouNeed. Retrieved 2020-06-26. 
 2. C.E. Shannon. "A Mathematical Theory of Communication" (PDF). Math.harvard.edu. Retrieved 2017-05-01. 
 3. "Communications: Process, Importance, Types, Barriers with Examples". Toppr-guides. 2018-06-11. Retrieved 2020-06-26.