Ewé
Ewé jẹ́ àkójọ pọ̀ orúkọ fún àwọn ẹtúntún igi oríṣríṣi tí a lè fojú rí.
Ìrísí rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ewé jẹ́ ohun tí ó ma ń sába rí pẹlẹbẹ, ó ma ń ní ilà tẹ́ẹ́rẹ́ láàrin bí ìṣẹ̀dá igi kọ̀ọ̀kan bá ṣe rí ni ewé rẹ̀ ṣe ma ń falà sára. Ewé sábà m ń hù sí ara tabí orí igi lọ́pọ̀ ìgbà, èyí náà tún dá lé irúfẹ́ ìṣẹ̀dá igi kọ̀ọ̀kan. Híhù igi sára ewé ma ń bẹ̀rẹ̀ láti àárin méjì. Apapọ̀ àárin igi ati ewé orí igi ni ó di ẹ̀ka igi. Ewé ma ń dàgba sókè látàrí omi ati ìtanṣán Oòrùn (photosynthesis) tí ó bá tan si ni ó fi ń gbéra sókè. [1][2][3][4] lọ́pọ̀ Ìgbà, gbogbo ewé kọ́ ló ma ń rí bákan náà, ọ̀pọ̀ ma ń dán lára,ọ̀pọ̀ sì ma ń hurun,ọ̀pọ̀ ma ń ní ẹ[[ẹ̀gún lára, nígbà tí ọ̀pọ̀ ma hani lọ́wọ́ [1]. [5] Ohun tí ó ma ń ṣokùn fà àwọ̀ olómi aró gírínì tí ewé ma ń ní ohun tí wọ́n pè ní kílórófì (chlorophyll). Èròjà yí ṣe.pàtàkì fún ìrú gọ́gọ́ ati ìdàgbàsókè ewé àti igi lápapọ̀, nítorí òun ni ó yíra padà sí óúnjẹ fún ewé ẹ́yìn tí ó bá ti gba ìtansán òrùn sára tán.
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 Esau 2006.
- ↑ Cutter 1969.
- ↑ Haupt 1953.
- ↑ Mauseth 2009.
- ↑ James et al 1999.