Eze V. B. C. Onyema III

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Eze V. B. C. Onyema III
Eze Onyema III of Ogwu-Ikpele

Reign 1976 - present[1]
Predecessor Eze Onyema II
Spouse Rebecca Nwanyiesigo Nnubia, Odobo of Ogwu-Ikpele
Issue
Roseline O. Ezuma, Margaret N. Orakwusi, Kenneth O. Onyema, Dominic Emeka Onyema, Catherine N. Emuchay, Emilia N. Onyema, Oscar N. Onyema,[2] and Wilfred Chukwuma Onyema
Father Eze Onyema II, Traditional ruler of Ogwu-Ikpele
Born Ogwu-Ikpele


Eze V. B. C. Onyema III (ọjọ́ ìbí; Oṣù Kejì Ọjọ́ Kẹtàlá, Ọdún 1927) jẹ́ olórí ìbílẹ̀ Ogwu-Ikpele ni ìjọba ìbílẹ̀ Ogbaru ní Ìpínlẹ̀ Anambra, Gúúsù ìlà oòrùn Nàìjíríà.[1] Òun ni arọ́pò bàbá rẹ̀, Eze Onyema II, àti ọ̀kan nínú àwọn aṣenilóore mẹ́ta ti Ìgbìmọ̀ Ìpínlẹ̀ Anambra ti Àwọn Alákooso Ìbílẹ̀.[3]

Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 "Anambra State Council of Igwe » ASA Canada". asacanada.com. Archived from the original on 14 August 2017. Retrieved 17 January 2022. 
  2. "Oscar Onyema". www.nse.com.ng. Retrieved Apr 13, 2020. 
  3. "The Source Magazine Online". www.thesourceng.com. Archived from the original on 6 April 2016. Retrieved 17 January 2022.