Fúnkẹ́ Akíndélé

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Fúnkẹ́ Akíndélé Bello
Funke Akindele.jpg
Fúnkẹ́ Akíndélé at the Africa Magic Viewers Choice Awards
ÌbíAkíndélé Olúfúnkẹ́ Ayọ̀túndé
Oṣù Kẹjọ 24, 1977 (1977-08-24) (ọmọ ọdún 43) [1]
Ikorodu, Lagos State, Nigeria
Iṣẹ́Actress, Film Producer

Fúnkẹ́ Akíndélé (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù kẹjọ ọdún 1977) tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń Jennifer jẹ́ òṣèrébìnrin àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Wọ́n bí Fúnkẹ́ sí ìlú Ìkòròdú, ní ìpínlẹ̀ Èkó lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà . Eré orí tẹlifíṣọ̀n kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "I need to know" ló mú un di gbajúmọ̀ ìlúmọ̀ọ́kà òṣèrébìnrin lọ́dún 1998 sí ọdún 2002. Lọ́dún 2009, ó gba àmìn ẹ̀yẹ tí "Africa Movie Academy Award" gẹ́gẹ́ bí òṣèré tó dára jùlọ. Sinimá àgbéléwò kan tí òun fúnra rẹ̀ kọ, tí ó sìn ṣe agbátẹrù rẹ̀, tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "Jennifer" mú un gbajúmọ̀ tó bẹ́ẹ̀ gẹ́ tí àwọn ènìyàn fi fún ní orúkọ ìnagijẹ, "Jennifer" tí gbogbo ènìyàn ń pè é. Lẹ́yìn èyí, ó tún ń ṣe sinimá aláwàdà tí ó pè ní "Jennifer Diary", sinimá yìí mú un gba àmìn ẹ̀yẹ òṣèrébìnrin aláwàdà tó dáńgájíá jùlọ lọ́dún 2016.[2] Fúnkẹ́ Akíndélé tí kópa nínú sinimá àgbéléwò to tì ju ọgọ́rùn-ún lọ. [3] [4] [5] [6]

Ààtò àwọn àmìn ẹ̀yẹ tí ó ti gbà[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọdún Ètò Àmìn Ẹ̀yẹ Àkànṣe Iṣẹ́ Èsì
2009 Africa Movie Academy Award Best Actress Leading Role Gbàá
2009 Nigeria Entertainment Awards Best Actress Jenifa Gbàá
2010 2010 Best of Nollywood Awards Best Actress in a Leading Role (Yoruba) Oguni Aiku Wọ́n pèé
2012 2012 Nigeria Entertainment Awards Best Actress Troj Gbàá
2012 Nollywood Movies Awards Best Actress (Indigenous) Emi Abata Gbàá
2012 Best of Nollywood Awards Best Actress (English) Married but Living Single Wọ́n pèé
Zulu African Film Academy Awards Best Actress Maami and The Return of Jenifa Gbàá
2013 2013 Nollywood Movies Awards Best Actress (Leading Role) Maami Wọ́n pèé
Best Actress (Indigenous) Gbàá
2014 2014 Nigeria Entertainment Awards Best Actress (Leading Role) Agnetta O’Mpa Gbàá
2014 Africa Magic Viewers Choice Awards Best Actress (Comedy) The Return of Sheri Koko Gbàá
ELOY Awards Brand Ambassador of the Year Omo Gbàá[7]
2016 2016 Africa Magic Viewers Choice Awards Best Actress In Comedy Role Jenifa's Diary Gbàá
Nigeria Entertainment Awards Best Actress Series Wọ́n pèé
Naija FM Awards Sitcom Of The Year Gbàá
Best Actress in Comedy Gbàá
Africa Entertainment Legend Awards Best Actress of the Year Gbàá[8]
2016 Ghana Movies Awards Best Actress Africa Collaboration A Trip to Jamaica Gbàá[9]
2017 Africa Magic Viewers Choice Awards Best TV Series Jenifa's Diary Gbàá[10]
Best Actress in a Comedy Movie or TV Series Gbàá[11]
A Trip to Jamaica Wọ́n pèé
2017 Nigeria Entertainment Awards Best Lead Actress Gbàá

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 1. "Just like Fúnkẹ́ Akíndélé, everyone got Eniola Badmus’ age wrong". The Net. The Net. Retrieved September 8, 2017. 
 2. "Watch Funke Akindele in season 4 trailer". Pulse Nigeria. 2016-01-26. Retrieved 2019-12-04. 
 3. "Nigeria's Top Website for News, Gossip, Comedy, Videos, Blogs, Events, Weddings, Nollywood, Celebs, Scoop and Games". Nigerian Entertainment Today. 2015-09-30. Retrieved 2019-12-04. 
 4. NJOKU, Benjamin (2010-01-01). "I didn't snatch anybody's husband - Funke Akindele". Vanguard News. Retrieved 2019-12-04. 
 5. Kabir, Olivia (2019-01-16). "Top facts about Funke Akindele state of origin". Legit.ng - Nigeria news. Retrieved 2019-12-04. 
 6. "Nollywood/ Nigeria No.1 movies/ films resources online". Nollywood/ Nigeria No.1 movies/ films resources online. 2019-10-21. Retrieved 2019-12-04. 
 7. "Omoni Oboli, Funke Akindele, Omawumi: All the winners from the 2014 ELOY awards - Lifestyle - Pulse" (in Èdè Jámánì). Pulse.ng. 2014-12-01. Retrieved 2016-12-17. 
 8. "Winners List - Ael Awards (Aela)". Aelaawards.com. Retrieved 2016-12-17. 
 9. "Ghana Movie Awards 2016: Funke Akindele wins best actress African collaboration - Movies - Pulse" (in Èdè Jámánì). Pulse.ng. Retrieved 2016-12-17. 
 10. Adeleke Afolayan (4 March 2017). "AMVCA 2017: See the full list of winners". The NET. 
 11. Chidumga Izuzu (4 March 2017). "Funke Akindele wins Best Actress in a Comedy". Pulse.Ng.