Jump to content

FUTA radio

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

FUTA Radio


Ile-ise agbohun safefe ti FUTA (93.1 MHz FM) ni ile-ise redio ti Federal University of Technology Akure ni Akure, Ondo State, Nigeria. O bere ise ni 19 November 2010.[citation needed] Ni odun 2015,ile ise redio naa jona nipase ijamba ina mo-na-mo-na; awon akekoo ti won kawe ni ale ni won gbiyanju lati dekun ina naa ki o ma ba tan kojá ile-ise naa ati ofisi olu-gbaniwole ni fafiti naa.[1][2] ITOKASI[edit source] ^ Kukogho, Samson (August 25, 2015). "Won padanu ohun to to milionu ni iye nipase ina mo-no-mo-no ti oganjo oru ni FUTA Redio". Pulse Nigeria. Retrieved August 29, 2021. ^ "Ina nla ni inu ogba Ile-ise agbohun safefe FUTA ba opolopo ogun ti o to milionu je". Sahara Reporters. August 24, 2015. Retrieved August 29, 2021.


Stub icon 1 Stub icon 2