Jump to content

Fadipe

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

 

Fadipe jẹ orúkọ ọmọ ọkùnrin ni orile-ede Naijiria ni ìpínlè Yoruba . Itumo re ni " Ifá san . Ati pe o wọpọ laarin awọn onigbagbọ ifa ( Oracle )

  • Nathaniel Fadipe

Nathaniel Akinremi Fadipe (2 October 1893 – 1944) je oniwadi Naijiria.

Kehinde FadipeListen (ojoibi 17 osu kini odun 1983) Osere ati akowe ara ilu oyinbo-Nigeria.