Jump to content

Fenda Lawrence

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Fenda Lawrence
Ọjọ́ìbícirca 1742
Saloum
AláìsíAfter 1780
Iṣẹ́Slave trader

Fenda Lawrence (1742[1] – lẹ́yìn 1780), jẹ́ olóko òwò ẹrú Áfíríkà tí ó ṣiṣẹ́ yìí ní Saloum, ìlú Kaur.

Fenda Lawrence gbé lẹ́gbẹ̀ẹ́ odò Gambia ní àwọn ọdún 1700s. Ní àdúgbò náà, ó jé òlùbádúna dúrà láàrin àwọn oníṣòwò Britain, France àti àwọn oníṣòwò Áfíríkà. Ó di ipò yìí mú lẹ́yìn ìgbà tí ó fẹ́ Òyìnbó kan. Lawrence ṣiṣẹ́ láti Saloum ìlú tí Kaur.[2] Ní ọdún 1772, Lawrence lọ sí Thirteen Colonies ti America láti ṣòwò.[3] Nígbà yìí, ó ti yapa láti ọ̀dọ̀ Oko òyìnbó tí ó fẹ́.[2]

Nígbà tí ó wọ ọkọ ojú New Britannia, Lawrence mú ẹrú márùn-ún pẹ̀lú ara rẹ̀. Ọkọ̀ náà déCharleston, South Carolina, lẹ́yìn ọjọ́ méjìdínlógójì tí ọ́ gbéra. Adarí ọkọ̀ náà, Stephen Deane, sì tẹ̀lé Lawrence lọ sí Georgia.[2]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Hassoum Ceesay: Gambian women: an introductory history. 1. Auflage. Fulladu Publishers, Gambia 2007
  2. 2.0 2.1 2.2 Akyeampong & Gates, Jr. 2012, p. 475.
  3. Holloway 2005, p. 49.