Feyisetan Fayose
Ìrísí
Feyisetan Fayose | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 8 Oṣù Kínní 1964 Nàìjíríà |
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Iṣẹ́ | Olùgbèjà-fún-ẹ̀tọ́-àwọn-ẹ̀dá-ènìyàn |
Olólùfẹ́ | Ayo Fayose |
Feyisetan Fayose jẹ́ onínúure-tí-ń-ta-ọ̀pọ̀-ènìyàn-lọ́órẹ, ọmọ bíbí ilẹ̀ Nàìjíríà, tí ó tún jẹ́ olùgbèjà fún ẹ̀tọ́ àwọn ẹ̀dá ènìyàn, àti pé obìnrin-àkọ́kó ti ìlú Ìpínlẹ̀ Èkìtì nígbà kan rí ni, gẹ́gẹ́ bí i aya Ayọ̀ Fáyọ́ṣe.[1][2][3]
Wọ́n bí Feyisetan Fayose ní ọjó kẹ̀jọ, osù kínní, ọdún 1964. Feyisetan jẹ́ ọ̀gá pátátá apá ẹgbẹ́ àwọn obìnrin onísẹ́-ìròyìn ti ìlú Èkìtì lápapọ̀.[4]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Ekiti First Lady warns against indiscriminate sex". Pulse Ng. Archived from the original on December 2, 2016. Retrieved December 20, 2016.
- ↑ "Wife of Gov. Fayose speaks on sex". News Agency of Nigeria. Archived from the original on December 13, 2016. Retrieved December 20, 2016.
- ↑ "FEYISETAN: The soothsayer, succour provider in Ekiti Govt House". Retrieved December 20, 2016.
- ↑ "Feyisetan Fayose Becomes NAWOJ Partroness". Ekiti State Government. Archived from the original on February 4, 2017. Retrieved December 20, 2016.