Firehiwot Dado

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Firehiwot Tufa Dado
Òrọ̀ ẹni
Ọjọ́ìbí9 Oṣù Kínní 1984 (1984-01-09) (ọmọ ọdún 40)
Assela, Arsi Zone
Sport
Orílẹ̀-èdèEthiópíà Ethiopia

Firehiwot Tufa Dado ni a bini ọjọ kẹsan, óṣu January, ọdun 1984 si Assela, Arsi jẹ elere sisa lóbinrin ti ọna jinjin. Tufa yege ninu Marathon ti New York City pẹlu wakati 2:23:15. Dado kopa ninu Marathon ti Rome City.

Àṣèyọri[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Dado kopa ninu ere awọn óbinrin ti Casablanca ni ọdun 2008[1]. Ni ọdun 2009, Firehiwot kopa ninu Marathon ti Rome pẹlu wakati 2:27:08[2]. Dado kopa ninu Marathon ti Frankfurt ni bi to ti gbe ipo kẹrin[3]. Ni ọdun 2010, Firehiwot kopa ninu Marathon ti Mumbai to si gbe ipo karun[4]. Firehiwot kopa ninu Marathon ti Florence ninu ọdun 2010. Ni ọdun 2011, Firehiwot kopa ninu ere ni Rome to si gbe ipo kẹta pẹlu wakati 2:24:13[5]. Ni ọdun 2011, Dado kopa ninu Marathon ti New York pẹlu wakati 2:23:14[6] Ni ọdun 2012, Dado kopa ninu Marathon ti Boston to si gbe ipo kẹrin[7]. Ni ọdun 2014, Dado yege ninu Marathon ti Prague pẹlu wakati 2:23:34[8].

Itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Casablanca Women's Race
  2. Rome Marathon
  3. Frankfurt Marathon
  4. Mumbai Marathon
  5. Rome Marathon
  6. New York Marathon
  7. Boston Marathon
  8. Prague Marathon