Àsìá ilẹ̀ Gùyánà
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Flag of Guyana)
Name | The Golden Arrowhead |
---|---|
Use | National flag |
Proportion | 3:5 |
Adopted | 26 May 1966[1] |
Design | A green field with the black-edged red isosceles triangle based on the hoist-side superimposed on the larger white-edged golden triangle, also based on the hoist-side, pointed toward the fly-side. |
Designed by | Whitney Smith |
Variant flag of Guyana | |
Use | National ensign |
Proportion | 1:2 |
Design | An elongated version of the above. |
Variant flag of Guyana | |
Use | Civil air ensign |
Proportion | 7:11 |
Design | British Civil Air Ensign combined with national flag of Guyana. May be flown at airports and from landed aircraft. |
Àsìá ilẹ̀ Gùyánà Jẹ́ àsíá orílẹ̀-édé, ó jẹ̀ àmì òpá áṣẹ àti ogun. Àsíá yìí jẹ́ aláwọ̀ márùn ùn; Pupa, Funfun, Èsúrú, Dúdú àti awọ̀ Ewéko. Áwọ̀ pupa tí ó dúró fún àyípadà dáradára, àwọ̀ funfun tí ó dúró fún odò àti omi kanga tí ó mọ́ , ésúrú tí ó dúró fún wààrà àti ọrọ̀ orílẹ̀-èdè náà, Dúdú dúró fún ìfaradà àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè náà àti àwọ̀ ewéko tí ọ ó dúró fún ètò ọ̀gbìn tí ọ́ fi ẹsẹ̀ múlẹ̀.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
àwọn ìtọ́ka sí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Flag Dates: by month". fotw.info.