Francisca Ikhiede
Ìrísí
Francisca Ikhiede | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 17 January 1996 Kaduna | (ọmọ ọdún 28)
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Iṣẹ́ | volleyball player |
Francisca Ikhiede jẹ obinrin elere fóólibọọlu ti ilẹ Naigiria ti a bini 17, óṣu January ni ọdun 1996 si ilu Kaduna. Elere naa ti ṣere fun team Custom ilẹ Naigiria ati team awọn obinrin Naigiria ti National[1][2].
Aṣeyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Ni ọdun 2019, Francisca ati awọn akẹgbẹ rẹ kopa ninu Ere Idije Fóólibọọlu lagbaye to waye ni Yaoundé, Cameroon nibi ti wọn ti jawe olubori ti o si gba Gold medal[3].
Itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ https://en.volleyballworld.com/en/beachvolleyball/worldtour/2019/wwch2019/women/teams/945728-nnoruga-franco/francisca_ikhiede?id=142825
- ↑ https://women.volleybox.net/francisca-ikhiede-p27299/clubs
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2023-03-18. Retrieved 2022-05-25.