Jump to content

Ganiu Bamgbose

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ganiu Abisoye Bamgbose (Dr GAB) jẹ ọmọ Naijiria, ọ̀mọ̀wé ati oniwadi. Lọwọlọwọ ó jẹ́ olùkọ́ni ni Ẹka Gẹẹsi, Ile-ẹkọ giga ti Ipinle Èkó, Nàìjíríà. Ganiu ni PhD kan ni Gẹẹsi ati pé ó ti ṣe àtẹ̀jáde méjèèjì ni àwọn ìwé agbègbè yìí àti ti káríayé nínú ẹ̀ka ìmọ̀ èdè (linguistics). Ó sì ti dásí àwọn ọ̀rọ̀ ti àyíká ẹ̀kọ́, òṣèlú, ìbáraẹnilò ati àṣà tí ó gbajúmọ̀ pèlú àlàyé tí ó kúnná nínú sísọ nípa wọn. Àwọn ìwádìí tí ó nífẹ̀ sí rèé ṣùgbọ́n kò pin si: Pragmatics, (pataki) àtúpalẹ̀ ọ̀rọ̀, gírámà Gẹ̀ẹ́sì, ìmọ̀-ọ̀rọ̀ àwùjọ tí ó jẹ́ mọ́ àṣà àti èdè Gẹ̀ẹ́sì ní Nàìjíríà.