Gelete Burka

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Gelete Burka
Òrọ̀ ẹni
Ọjọ́ìbíOṣù Kínní 23, 1986 (1986-01-23) (ọmọ ọdún 38)
Kofele, Oromia Region
Height5 feet 3 inches (1.60 m)
Weight95 pounds (43 kg)
Sport
Orílẹ̀-èdè Ethiopia
Erẹ́ìdárayáWomen's athletics

Gelete Burka Bati ni a bini ọjọ kẹta leelogun, óṣu January, ọdun 1986 jẹ elere sisa lobinrin ilẹ Ethiopia to da lori ere sisa ti arin ati ọna jinjin. Abi Arabinrin naa si Kofele, Zone ti Arsi ni Oromia[1][2].

Àṣèyọri[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Gelete kopa ninu idije agbaye ti IAAF ni ọdun 2006. Arabinrin naa gba ami ẹyẹ ti ọla lẹẹmẹta ninu idije agbaye ti inu ile[3]. Ni ọdun 2008, Gelete gba ami ẹyẹ ti ọla ti wura ni ere sisa ti metres ti 1500. Arabinrin naa kopa ninu idije agbaye lori ere sisa lati ọdun 2005 de 2011. Arabinrin naa ṣoju fun ilẹ Ethiopia ninu olympics ni ọdun 2008 ati 2012. Gelete gba ami ẹyẹ ti ọla ti idẹ ni ere gbogbo ilẹ Afirica[3]. Burka bẹrẹ ọdun 2013 pẹlu yi yege ni Cross Internacional Juan Muguerza. Gelete Burka gbe ipo kẹjọ ni wakati 30:26.66 ninu ere sisa ti summer olympics ti awọn óbinrin ti metres ẹgbẹrun mẹwa[4].

Itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Gelete Profile
  2. Burika aim at World Cross return
  3. 3.0 3.1 All Africa Games
  4. Olympics 10,000