Mother of George

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti George Mother)
Mother of George
Fáìlì:Mother of George poster.jpg
Theatrical release poster
AdaríAndrew Dosunmu
Olùgbékalẹ̀Patrick S. Cunningham
Òǹkọ̀wéDarci Picoult
Àwọn òṣèré
Ìyàwòrán sinimáBradford Young
OlùpínOscilloscope Laboratories
Déètì àgbéjáde
  • Oṣù Kínní 18, 2013 (2013-01-18) (Sundance Film Festival)
  • Oṣù Kẹ̀sán 13, 2013 (2013-09-13) (United States)
Àkókò106 minutes
Orílẹ̀-èdè
  • Nigeria
  • United States
ÈdèEnglish/Yorùbá

Mother of George jẹ́ ere ońìṣè kan ni ọ̀dùń 2013 ńì órìlẹ́-èdé Ńáìjírì tì Andree Dòsùńmù jẹ́ òlùdárì rẹ́. directed byAndrew Dosunmu[1]èré yì sọ̀ ńìpá igbeyawo tuntun káń tì wọ̀ń wá látì orìlè-èdé Ńáìjìríá tì wọ̀ń sìńgbè ńì òkè ókùń ńì órìlè-èdé Broklìń ,tì wọ̀ń ńì ìlè íṣẹ́ káń tì áwọ̀ń èyáń jẹ́ tì wọ̀ń sì mù ,sùgbòń àwọ̀ń ọ̀kọ́ átì ìyáwò yì ńì ìṣòrò ọ́mọ̀ bíbì. Pátrìck S.Cunningham ńì ò gbè èré yì jádé.[2]and Rhea Scott.[3]

Èré yì kòpá ńìńù ìjádè káń ńì orìlè-edé U.S. ńì ọ̀dùń 2013 tì Sundance Film Festival[4] Cinematographer Bradford Young won Sundance 2013's Cinematography Award: U.S. Dramatic for his work on this film andAin't Them Bodies Saints.[4][5]Mother of George was also selected as the closing night film at the 2013 Maryland Film Festival[6]

Áwọ̀ń árá ókè òkùń gbá èré òńìṣè yì tìwọ̀ń sì tùń báwọ̀ń pìń látì ọ̀dọ̀ Oscilloscope Laboratories[7]

Ágbèkálẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Èré òńì ṣè yì bẹ́rẹ̀ pẹ́lù ìgbèyáwò Awọ̀ń ara orile-ede Ńáìjírìá lárìń tọ̀kọ̀táyà tì ọ́kọ̀ jẹ́ ,Áyọ̀dèlé Ayodele (Issach de Bankolé) tì ìyàwò sìńjẹ́ Ádéńìkẹ́ (Danai Gurira) Balogun. Iya ọ́kọ̀ Ádéńìkẹ́ fun Àdéńìkẹ́ ńì ilẹ́kẹ̀ tì yì ó fìṣè ábìyámọ̀. Mama Ayo (Bukky Ajayi) ṣùgbọ̀ń ńì àlẹ̀ ìgbèyáwò tọ́kọ̀ táyá ńì

anọ̀ṣèpọ̀ pèlù árá wọ̀ń ,sìbẹ́ ńáà Ádèńìkẹ́ ó fì ìńù ṣoyùń .Ni ayì mọ̀yè Igba ńì Ádéńìkẹ́ ti jẹ́ jìjẹ́ tì osi tì mu mí mù , pá bò nì gbógbò rẹ́ jásì bẹ́ńà ńì Iya ọ́kọ̀ ẹ́ dálámù pe ọ́hùń fẹ́ ri ọ́mọ̀ mọ̀ óhùń . Ńì igbá tì wọ̀ń dè ílé íwòsáń ,Dọ́kìtá sọ̀fùń wọ̀ńpé Ádéńìkẹ́ lérì írọ̀lọ́wáń ṣùgbọ̀ń Àyọ̀dèlé ọ́kọ̀ rẹ́ ò gbá.

Ṣádè (Yaya DaCosta) sọ́fùń Ádèńìkẹ́ ńìpá kì ó gbá ọ́mọ̀ tọ̀, ṣùgbọ̀ń ókọ̀ jálẹ́ óńì óhùń óbì ómò óhùń pẹ́lù ínù ohùń. Iya ọ́kọ̀ da ba pe ki aburo ọ́kọ̀ Ádèńíkẹ̀,Biyi(Tony Okungbowa) Ati Ádéńìkẹ́ fun ra ẹ́ Ki wọ̀ń jọ̀ ńi ájọṣèpọ̀. Biyi fárìgá pe ohun óṣé,ṣùgbọ̀ń ola dá gbá . Lẹ́yìń ńá Ádèńìkẹ́ lòyùń tì Àyọ̀dèlé ọ́kọ̀ rẹ̀ rò pè óhùń ló ńì ọ̀mọ̀.

Ẹ́rì ọ́káń òjẹ́ kì Àdèńìkẹ́ gbádùń tìtì tí ó fí sọ̀ ótọ̀ fùń ọ̀kọ́ rẹ́. Áyọ̀dèlé kùrò ńìńù ígbéyàwò ńáà tì ó sì dòjùkọ̀ iyá rẹ́ . Èré ónìṣè yì párì ńìbì tì Ádèńìkẹ́ tì fẹ́ bì ọ́mọ̀ tì ọ́kọ̀ rẹ́ sì lọ̀báwọ̀ń ńì ílé íwòsáń.

Awọ̀ń óṣèré[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • [[Isaach de Bankolé] gẹ́gẹ́ bí Ayọ̀délé

==Árìwìsì Awọ̀ń èyáń nipa ere óńìṣè yì==Ńìńù ọ́gọ̀rùń èré yì gbá 93% ni Rotten Tomatoes based on 40 reviews, with an average rating of 7.1 out of 10. Áwọ̀ń èyáń tùń rìpè èré yì yátọ̀ átìpè ,George Mother yì ńì ágbárá tì ó sì ṣè áfìháń àwọ̀ń óṣèré ńlà

References[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. McCarthy, Todd. "Mother of George: Sundance Review". The Hollywood Reporter. The Hollywood Reporter. Retrieved March 5, 2013. 
  2. "Mother of George - The Hollywood Reporter". www.hollywoodreporter.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2017-03-06. 
  3. "Little Minx Delivers "Tom Clancy's Ghost Recon Alpha" for Ubisoft" (in en-US). Cartoon Brew. 2012-05-16. http://www.cartoonbrew.com/biz/little-minx-delivers-tom-clancys-ghost-recon-alpha-for-ubisoft-62999.html. 
  4. 4.0 4.1 "Sundance Festival Award Winners". Sundance Film Festival. Archived from the original on 2013-01-29. Retrieved 2013-08-31. 
  5. "Mother of George". Roger Ebert. Godfrey Cheshire, September 13, 2013
  6. "Mother of George". Maryland Film Festival. Archived from the original on 2013-06-07. Retrieved 2013-08-31.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  7. "Oscilloscope Acquire's Andrew Dosonmu's Mother of George". Deadline. Deadline.com. Retrieved 14 March 2013. 

External links[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]