Hakeem Osagie

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Hakeem Iguodalo Bello Osagie

Lọ́yà ni, ‘Petroleum Economist ni ó sì tún jẹ́ ‘financial technocrat’. A bí i ní ọjọ́ kọkiàndínlọ́gbọ̀n oṣù kéjì ọdún 1952. Èkó ni a ti bí i. Àwọn ilé-ẹ̀kọ́ tí ó lọ ni King’s College, Lagos 1966-1971, Oxford University, Oxford 1973-1976, Cambridge University, Cambridge 1976-1979, Havad Business School, USA 1978-1980, Nigerian Law School 1981-1982. Òun ni ó jẹ ‘special assistant to the presidential adviser on petroleum and energy’ abe Sheu shegari. Òun ni akọ̀wé Nigerian Liquefied Natural Gas (NLNG) committee tí ó ṣètò bí NLNG project ṣe bẹ̀rẹ̀. Ilé-iṣẹ́. Lóóyà Udoma àti Bello Osagie ni ilé-iṣẹ́ lọ́ọ́yà wọn.