Jump to content

Helen Oyeyemi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Helen oyeyemi)
Helen Oyeyemi
Helen Oyeyemi in January 2021
Ọjọ́ ìbíHelen Oyeyemi
10 Oṣù Kejìlá 1984 (1984-12-10) (ọmọ ọdún 40)
Ibadan, Nigeria
Iṣẹ́Writer
GenreFiction
Notable awardsPEN Open Book Award

Helen Oyeyemi FRSL (tí a bí ní ọjọ́ kẹwàá oṣù Kejìlá ọdún 1984) jẹ́ òǹkọ̀wé ilẹ̀ ọba àti oǹkọ ìtàn kéékèèké

Oyeyemi ni a bí ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, tí a sì tọ́ ní Lewisham, South London láti ìgbà tí ó ti wà ní ọmọ ọdún mẹ́rin.[1][2] Oyeyemi kọ ìwé rẹ̀ àkọ́kọ́, ìyẹn The Icarus Girl, nígbà tí ó ń kàwé fún A-levels[3]Cardinal Vaughan Memorial School. Ó lọ sí Corpus Christi College, Cambridge. Láti ọdún 2014 ni ilé rẹ̀ ti wà ní Prague.[2][4]

Iṣẹ́ tó yàn láàyò

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Nígbà tí ó wà ní kọ́lẹ́ẹ̀jì, eré rẹ̀, Juniper's, ni àwọn akẹgbẹ́ rẹ̀ ṣe, tí Methuen sì tẹ̀ ẹ́ jáde ní ọdún 2014.[5][6] Ní ọdún 2007, Bloomsburygbé ìwé Oyeyemi kejì jáde , The Opposite House, tí ìmísí rẹ̀ wá láti inú Cuban mythology.[7][8] Ìwé rẹ̀ kẹta, White Is for Witching, ní Picador gbé jáde ní oṣù karùn-ún ọdún 2009. Ìwé yìí ni ó wà ní ipo tí ó kẹ́yìn nínú ipele àmì ẹyẹ ti Shirley Jackson Award [9] ó sì gba Somerset Maugham Award[10] ni ọdún 2010.Ni ọdún 2009, Oyeyemi jẹ́ ọ̀kan lára àwọn tí a kọ sínú orúkọ àwọn obìnrin tí ó wà nínú Venus Zine's "25 under 25" list.[11] Ìwé rẹ̀ kẹrin, Mr Fox, ni Picador gbé jáde ní oṣù kẹfà ọdún 2011,[12] Ní ọdún 2013,orúkọ rẹ̀ wà nínú Granta Best of Young British Novelists list.[13] Ìwé rẹ̀ karùn-ún, Boy, Snow, Bird, ni Picador gbé jáde ní ọdún 2014.[14][15] Boy, Snow, Bird wọ ipele tí ó kẹ́yìn fún Los Angeles Times Book Prize ní ọdún 2014.[16]

Oyeyemi gbé What Is Not Yours Is Not Yours, àkójọpọ̀ ìtàn , jáde ní ọdún 2016.[17][18] Ìwé yìí What Is Not Yours Is Not Yours ni ó gba 2016 PEN Open Book Award: fún ìwé lítírésọ̀ tí ó pọ̀, tí ó sì tayọ, láti owó olùṣẹ̀dá àwọ̀.[19]

Gingerbread, ni a gbé jáde ní ọjọ́ karùn-ún, oṣù kẹta ọdún 2019.[20] Peaces, ni a gbé jáde ní ọjọ́ Kínní, oṣù kẹrin ọdún 2021.[21]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Quinn, Annalisa (7 March 2014). "The Professionally Haunted Life Of Helen Oyeyemi". NPR. Retrieved 31 January 2021. 
  2. 2.0 2.1 Hoggard, Liz (2 March 2014). "Helen Oyeyemi: 'I'm interested in the way women disappoint one another'". The Guardian (London). https://www.theguardian.com/books/2014/mar/02/helen-oyeyemi-women-disappoint-one-another. 
  3. Jordan, Justine (11 June 2011). "Mr Fox by Helen Oyeyemi – review". The Guardian. Retrieved 30 January 2012. 
  4. Bradshaw, M. René (16 March 2016). "What is Not Yours is Not Yours by Helen Oyeyemi". The London Magazine. Retrieved 20 November 2016. 
  5. bloomsbury.com. "Juniper's Whitening". Bloomsbury (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-01-27. 
  6. "Prolific writer Oyeyemi shortlisted for BBC short story award | Premium Times Nigeria" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-09-18. Retrieved 2022-05-27. 
  7. "Oyeyemi's 'Opposite House'". Tell Me More. 26 June 2007. NPR. 
  8. D'Erasmo, Stacey (27 February 2014). "Helen Oyeyemi's 'Boy, Snow, Bird' turns a fairy tale inside out". The Los Angeles Times. 
  9. "2009 Shirley Jackson Awards Winners". The Shirley Jackson Awards. Retrieved 2020-05-29. 
  10. "Helen Oyeyemi - Literature". literature.britishcouncil.org. Retrieved 2020-05-29. 
  11. Woman.NG (2016-03-16). "You'll Want To Get Helen Oyeyemi's New Book 'What is Not Yours is Not Yours' After Reading These Reviews". Woman.NG (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2020-10-29. Retrieved 2020-05-29. 
  12. Sethi, Anita (13 May 2012). "Mr Fox by Helen Oyeyemi – review". The Observer. https://www.theguardian.com/books/2012/may/13/mr-fox-helen-oyeyemi-review. 
  13. "Granta 123: Best of Young British Novelists 4". Granta (123). 2013. http://www.granta.com/Archive/123. 
  14. Clark, Alex (22 March 2014). "Boy, Snow, Bird review – Helen Oyeyemi plays with myth and fairytale". The Guardian. https://www.theguardian.com/books/2014/mar/22/boy-snow-bird-review-helen-oyeyemi. 
  15. Quinn, Annalisa (7 March 2014). "The Professionally Haunted Life of Helen Oyeyemi". NPR. 
  16. Swanson, Clare (March 5, 2015). "L.A. Times Book Prize Finalists Announced". https://www.publishersweekly.com/pw/by-topic/industry-news/awards-and-prizes/article/65774-2014-l-a-times-book-prize-finalists-named.html. 
  17. Oyeyemi, Helen (8 March 2016) (in en). What Is Not Yours Is Not Yours. Place of publication not identified: Riverhead Books. ISBN 9781594634635. 
  18. Van Den Berg, Laura (18 March 2016). "'What Is Not Yours Is Not Yours,' by Helen Oyeyemi". The New York Times. https://www.nytimes.com/2016/03/20/books/review/what-is-not-yours-is-not-yours-by-helen-oyeyemi.html. 
  19. "2017 PEN America Literary Awards Winners", Pen America, 22 February 2017.
  20. Charles, Ron (26 February 2019). "Review | Helen Oyeyemi's 'Gingerbread' recipe: Fairy tales with a dash of surrealism" (in en). The Washington Post. https://www.washingtonpost.com/entertainment/books/helen-oyeyemis-gingerbread-recipe-fairy-tales-with-a-dash-of-surrealism/2019/02/26/7ec22c84-3930-11e9-a2cd-307b06d0257b_story.html. 
  21. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :1