Àwọn Ajọọmọnìyàn
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Hominoidea)
Àwọn Ajọ̀bọ Apes[1] Temporal range: Late Oligocene - Recent
| |
---|---|
Lar Gibbon (Hylobates lar) | |
Ìṣètò onísáyẹ́nsì | |
Ìjọba: | |
Ará: | |
Ẹgbẹ́: | |
Ìtò: | Àwọn Akọ́dièyàn {Primates}
|
Suborder: | |
Infraorder: | |
Parvorder: | |
Superfamily: | Àwọn Aríbíèyàn (Hominoidea) Gray, 1825
|
Families | |
Hylobatidae |
Ajọ́bọ (Ape) je eyikeyi ninu ébi gbangba Àwọn Aríbíèyàn (Hominoidea) ti awon akodieyan, ninu won na ni awon eniyan wa.
Labe sistemu iyasoto lowo awon ebi meji awon aribieyan lowa:
- ebi Hylobatidae to ni apa 4 ati iru eya 14 awon gibo, ninu won ni Gibo Lar ati Siamang wa, lapapo won je awon ajobo kekere.
- ebi awon Ajoeyan (Hominidae) ninu won ni awon osa, awon gorilla, awon eniyan ati awon orangutan[1][2] lapapo a mo won bi awon ajobo ninla.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 Àdàkọ:MSW3 Groves
- ↑ M. Goodman, D. A. Tagle, D. H. Fitch, W. Bailey, J. Czelusniak, B. F. Koop, P. Benson, J. L. Slightom (1990). "Primate evolution at the DNA level and a classification of hominoids". Journal of Molecular Evolution 30 (3): 260–266. doi:10.1007/BF02099995. PMID 2109087.