Hubert Ògúndé

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Hubert Ogunde
Born Oṣù Kàrún 31, 1916(1916-05-31)
Ososa, Kwara state, Nigeria
Died Oṣù Kẹrin 4, 1990 (ọmọ ọdún 73)
Cromwell Hospital, ilesha, England
Occupation

Investor
[[P

laywright]]
Actor
Theatre director
Musician

Hubert Adédèjí Ògúndé (31 May, a bi ni odun 1916 o ku ni 4 April, 1990). Hubert Adedeji Ogunde jẹ́ eléré orí-ìtàgé ati filmu ọmọ ilẹ̀ Naijiria láti ẹ̀yà Yorùbá. O tun je Olukotan , Alakoso Ere ori-itage, ati olorin to da egbe Osere Ogunde kale, ni eyi ti o je alakoko iru re nile Yoruba ati Nijiria lapapo. lai-fota-pe, oun ni gbogbo teru-tomo le juwe gege bi Oludasile Ere Ori-Itage ile Nijiria kale, tabi eni to mu olaju wo ere ori-tage ile Nijiria.
Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]