Jump to content

Àwọn ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Human right)
Magna Carta je gbigbejade ni Ilegeesi ni 1215.

Àwọn ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn ni "awo eto ipile ati ominira ti gbogbo awon omo eniyan leto si."[1] Awon olugbowo ero yi un tenumo pe gbogbo awon eniyan ni awon ajemonu nitoripe won je omo eniyan.[2] Nitorie awon eto omoniyan je gbigba bi ti eyi to je alagbalaaye ati bakanna. Iru awon ajemonu bayi le wa gege bi awon asa awon iwuwa eniyan gangan, gege bi asa iwa tito tabi awon eto eda ti o ni idi pataki, tabi gege bi awon eto olofin boya ninu orile-ede tabi ninu ofin kariaye.[3] Sibesibe, ko si ikoenu lori kini ohu pato to je tabi ti ko je eto omoniyan lona kankan, be si ni ero awon eto omoniyan bi afoyemo ti je ohun ijiyan ati igbeyewo ninu imo oye.

ero odeoni nipa awon eto omoniyan dide leyin isele Ogun Agbaye Keji, gege bi idahun si Ipaniyanrun àwon Ju, eyi fa itowobowe Ìkéde Akáríayé fún àwọn Ẹ̀tọ́ Ọmọnìyàn latowo United Nations General Assembly ni 1948.



  1. Houghton Mifflin Company (2006)
  2. Feldman, David. Civil Liberties & Human Rights in England and Wales. Oxford University Press. pp. 5. l
  3. Nickel, James (2009). Zalta, Edward N., ed. "Human Rights". The Stanford Encyclopedia of Philosophy.