Hunturu (Igba Otutu)
Ìrísí
Igba otutu jẹ akoko otutu ati kurukuru pupọ ati ni awọn orilẹ-ede kan ọpọlọpọ omi yinyin wa nigbati igba otutu ba de.[1]
Igba otutu ni Afirika
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ni ilẹ Afirika, igba otutu wa lati Kẹrin si Oṣu Kẹjọ [2] ni ọdun kọọkan.
Igba otutu ni Europe
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ni awọn orilẹ-ede Yuroopu, igba otutu jẹ eyiti o wọpọ julọ lati Oṣu Kini si Oṣu Kẹrin ni gbogbo ọdun.[1]