Iṣẹ́ Fàyàwọ́
Ìrísí
Iṣẹ́ fàyàwọ́ ni gbígbé ẹrù, ohun èlò, tàbí èèyàn lọ́nà àìtọ́ láti ibikan sí ibòmìíràn. Ó le jẹ́ láti ìlú kan sí ìlú mìíràn, tàbí láti orílẹ̀-èdè kan sí orílẹ̀-èdè mìíràn.