Iṣẹ́ Iranṣẹ Igbagbọ Ihinrere Kariaye (The Gospel Faith Mission International)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àdàkọ:Infobox Christian denomination Iṣẹ́ Iranṣẹ Igbagbọ Ihinrere Kariaye (GOFAMINT)) jẹ ọkan gboogi ninu awon elesin Kristieni lati orilẹ-ede Naijiria ti a ti ọwọ́ Rubeni Akinwalere George dá silẹ ni agbegbe Iwaya ni adugbo Yaba ni ilu Eko ni ọdun 1956. [1]

Iṣẹ́ Iranṣẹ Igbagbọ Ihinrere Kariaye ti ni ẹ̀ka kaakiri awọn orilẹ-ede ni agbaaye bi ni orilẹ-ede Gẹẹsi lati ọdún 1983 [2] àti ní ilu Amẹrika lati ọdun 1985. [3]

Iṣẹ́ Iranṣẹ Igbagbọ Ihinrere Kariaye (GOFAMINT) tẹdo si Ìlú Ìhìnrere, ni Kilomita ogoji, opopona marosẹ ti o ti Eko wa si Ibadan, Aṣeeṣe, Ipinlẹ Ogun. Nigbati Olu ile-iṣẹ Iṣẹ́ Iranṣẹ Igbagbọ Ihinrere Kariaye wa ni Gbongan Ihinrere, Ọjọọ, oju ọna Ọyọ, Ibadan, Ipinlẹ Ọyọ, sugbọn laipẹ, wọn o ma kó olu ile iṣẹ Iṣẹ́ Iranṣẹ Igbagbọ Ihinrere Kariaye lọ si Ogunmakin ti Ipinlẹ Ogun.

Àwòrán ìdámọ̀ ìjọ GOFAMINT
  1. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2012-03-25. Retrieved 2019-08-26. 
  2. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2012-03-25. Retrieved 2019-08-26. 
  3. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2012-03-25. Retrieved 2019-08-26.