Ibrahim Chatta
Ìrísí
Ibrahim Chatta ( tí a bí ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹwàá ọdún 1970) jẹ́ gbajúgbajà olùdarí àti òṣèrè sinimá àgbéléwò ọmọ Yorùbá láti Ìpínlẹ̀ Kwara lórílẹ̀ Nàìjíríà .[1]
Ìgbé-ayé Rẹ̀ Ní Ìbẹ̀rẹ̀ Pẹ̀pẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ibrahim Chatta kò fi bẹ́ẹ̀ kàwé pùpọ́. Ìpele kẹta ẹ̀kọ́ sẹ́kọ́ńdìrì ní ó ti fi ẹ̀kọ́ kíkà sílẹ̀. Ò wá pápá kẹ́kọ̀ọ́ lóríṣiríṣi nípa ère sinimá àgbéléwò. Kí ó tó di ìlúmọ̀ọ́ká, ọ̀pọ̀ ni iṣẹ́ ló tí ṣe. Àkọsílẹ̀ kan sọ pé ó ti fìgbà kan ṣíṣe apèròsọ́kọ̀. [2]
Àwọn Ìtọ́kasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Olatunji, Dami (2018-08-15). "Top facts from the biography of a Nollywood actor Ibrahim Chatta". Legit.ng - Nigeria news. Retrieved 2019-10-21.
- ↑ "Ibrahim Chatta Biography: Age & Movies". 360dopes. 2018-07-14. Retrieved 2019-10-21.