Jump to content

Ibrahim Tahir

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àdàkọ:Use mdy dates

Talba
Ibrahim Tahir
Ọjọ́ìbíIbrahim Tahir
Tafawa Balewa, Northern Region, British Nigeria
AláìsíDecember 8, 2009
Cairo, Egypt,
Iléẹ̀kọ́ gígaBA (sociology)
PhD (social anthropology)
King's College, Cambridge
Iṣẹ́Sociologist, writer, politician
Gbajúmọ̀ fúnTraditionalist conservatism
Notable workThe Last Imam (1980)

Ibrahim Tahir (tí ó kú lọ́jọ́ kẹsàn-án oṣù Kejìlá ọdún 2009) jẹ́ onímọ̀ àyíká (sociologist), oǹkọ̀wé àti òṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè ní ètò-òṣèlú ẹlẹ́ẹ̀kejì Nigeria. Bákan náà, ó jẹ́ ọ̀kan gbòógì nínú ẹgbẹ́ alákatakítí Kaduna mafia. Kí ó tó dárapọ̀ mọ́ òṣèlú, ó jẹ́ onímọ̀ àyíká tí ó gbajúmọ̀ nínú òye Traditionalist conservative.[1]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Haruna, Mohammed. "Tahir: The Death of a Radical Conservative". Gamji.com.