Idiat Adebule
Ìrísí
Dr Oluranti Adebule, (ti a bi ni Ojo ketadinlogbon osu kokanla odun 1970) je oloselubinrin omo Yoruba lati ipinle Eko lorile-ede Naijiria. [1] O je omo bibi idile Idowu-Esho ti iku Ojo Alaworo ni ijoba Ibile Ojo, ni ipinle Eko. Oun ni igbakeji Gomina Ipinle Eko nigba ijoba Gomina Akinwunmi Ambode ti saa won sese pari ni odun 2019. Obafemi Hamzat ni o ropo re gegebi igbakeji Gomina.[2]
Awon Itokasi
- ↑ "Oluranti Adebule". Wikipedia. 2016-11-25. Retrieved 2019-09-25.
- ↑ "DR KADRI OBAFEMI HAMZAT - Lagos State Government". DEPUTY GOVERNOR, LAGOS STATE|DR KADRI OBAFEMI HAMZAT - Lagos State Government. Retrieved 2019-09-25.