Jump to content

Ifaluyi Isibor

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ifaluyi Isibor jẹ́ olóṣèlú àti onímọ̀ nípa àlùmọ́ọ́nì ilẹ̀ tí ó ṣojú ẹkùn ìpínlẹ̀ Egor / Ikpoba Okha ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin láti ọdún 2007 sí ọdún 2011. [1] [2]