Jump to content

Igi Àgbọn

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Igi àgbọn tí ìnagijẹ rè ń jẹ́ (Cocos nucifera) ní èdè Latin jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ẹbí igi tí ó ń jẹ́ (Arecaceae), tí ó sì njẹ́ ọ̀kan ṣoṣo tí ó ṣẹ́kù nínú àwọn igi ti wọ́ ń pè ní (genus Cocos).

Èso àgbọn wúlò púpọ̀ nítorí ẹgbàá-gbèje ìwòs̀an tí ó sòódó sínú rẹ̀, níbi jíjẹ, mímu omi rẹ̀, lílò rẹ̀ láti fi ṣe oògùn tàbí ìpara àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Àgbọn yàtọ̀ gidi gidi sí àwọn èso tí ó kù nítorí inú àti omi rẹ̀ tí mọ́ kangá.[1]

Àgbọn tí ó bá ti gbó kákạ́ ni wọ́n ma ń jẹ tàbí fi ṣe òróró tí a ń lò fún ohun jíjẹ, pàá pàá jùlọ àgbọn gbígbẹ. Eérú tàbí èédú tí wọ́n bá rí kó níbi jíjó kókódu rè ni wọ́n fi ń ṣe àwọn ohun èlò mìíràn.[2]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "5 Health and Nutrition Benefits of Coconut". Healthline. 2019-07-23. Retrieved 2019-12-06. 
  2. "Coconut 101: Nutrition Facts, Health Benefits, Beauty Benefits, Recipes". EverydayHealth.com. 2019-07-12. Retrieved 2019-12-06.