Igi pako
Ìrísí
Ìgi Pákò jẹ́ ohun tí a má ní ló láti fọ eyin ni ile Yorùbá, Èyí tí wá kí ohun tí àwọn aláwọ̀ funfun má ń pé ni BÚRỌ́Ọ̀ṢÌ ( Brush) ó tó dé. Ó ní ará Igi kàn tí wọn tí máa ń gbé pákò jáde. Ní ilé Yorùbá wá gbàgbó pé Ìrun pákò a máa jẹ kí eyin bó funfun. Bákan náà igi pákò yìí náà máa ń jẹ́ gbígbà àgbò. Fún àpeere, ẹnití ọ bá rẹ̀ tí ẹnu rẹ̀ sí koró, wá gbàgbó pé bí irú ẹni bẹ́ẹ̀ ba rin IGI Ewúro gẹgẹ bí pákò láti fi ẹnu, ẹnu rẹ̀ ò ní koró mọ́. Yóò sílè jẹun.
Àwọn kan a má mú ìgi pákò ṣíṣe gẹgẹ bí iṣẹ́