Ijanikin
Ìrísí
Ijanikin jẹ ìlú tí ó wà ní agbègbè Ọ̀tọ̀-Àwórì ní abẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ Ọ̀jọ́ ní ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà.
Eniyan
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ijanikin gan-an ni awon Aworis ti wa nibe niwon igba ti won gbagbo pe awon ni won koko gbe ilu naa. [1] [2] Àṣà ìbílẹ̀ ìlú náà ni olóòṣà tí wọ́n ń pè ní Onijanikin Ijanikin . [3]
Ẹkọ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]̀ijànikin jẹ́ ilé si ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọ́n ilé-ẹkọ́ olókìkí pẹ̣̀lu kọ́lẹ̀jì obìnrin ti ìjọba àpapọ̀ ti ̀ilú Èkó, Ọ̀tọ̀/Ìjanikin ní ilé-̀iwé girama ìjọ̣ba ìpínl̀ẹ Èkó, Ọ̀tọ̀/Ìjànikin [4] [4]
Awọn itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Ruhollah Ajibọla Salakọ (1998). Ọta: Biography of the Foremost Awori Town. Penink Publicity & Company. https://books.google.com/books?id=ypcPAQAAMAAJ.
- ↑ E. A. Ajayi. A History of the Awori of Lagos State. Adeniran Ogunsanya College of Education. https://books.google.com/books?id=TH0uAQAAIAAJ.
- ↑ A. G. A. Ladigbolu (prince.). Nigerian at 47, 1960-2007: prominent achievers in Nigeria. Lichfield Communications. https://books.google.com/books?id=pQQLAQAAMAAJ.
- ↑ Lagos State (Nigeria). Ministry of Information and Culture. Public Information Dept (1991). Focus on [name of Administrative Division]: Badagry. The Dept.. https://books.google.com/books?id=atAuAQAAIAAJ.