Ijo Anglika

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Ìjọ Ánglíkà[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ìjọ Ánglíkà jẹ́ ìjọ tí o tóbi ṣe ìkẹrin nínú àgbáríjọ pọ̀ àwọn ọmọ lẹ́yìn Krístì káàkiri àgbáyé pẹ̀lú ọmọ ìjọ tí ó tó miliọ̣nu márun-lé-lọ́gọ́rin eniyan.[1]

  1. http://www.anglicancommunion.org/structures/member-churches.aspx