Jump to content

Ijọidi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Ijoidi)

Apá gúúsù ilẹ̀ Nigeria ni a ti rí àwọn tí wọ́n ń sọ èdè yìí. Èdè náà ni a mọ̀ sí Defaka àti Ijọ. Jenewari àti Williamson (1989) ni wọ́n ṣe àgbékalẹ̀ àtẹ isálẹ̀ yìí

Nínú àtẹ yìí, a rí ‘Proto-Ijoid’ tí ó pín sí Defaka ati Ijọ. Ijọ pín Ìlà-oòrùn àti ìwọ̀ oòrùn. Lábé ìlà-oòrùn ni a ti rí: Nkọrọ, Ibani, Kalabari, Kirike (Okrika), Nembe ati Akaha(Akassa). Lábẹ́ ìwọ̀-oòrùn ni a ti rí : Izon, Biseni, Akita (Okordia), Oruma