Jump to content

Ilé

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ilé tí a tún ńndà pè ní Ibùgbé jẹ́ ibi tàbí àyè tí a lè ma sùn tàbí gbé pẹ̀lú àwọn ẹbí wa.[1]

Ohun èlò ìkọ́lé

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ilé lọ́pọ̀ ma ń jẹ́ ohun tí wọ́n ms ńa fi igi àti ikí kọ́bláyé àtijọ́. Irúfẹ́ ilé báyí ni wọ́n ń ń pè ní Abà. Àmọ́ láyé òde òní, oríṣríṣi ohun èlò ni wọ́n fi ń kọ́lé, àwọn ohun èlò bí: iyẹ̀pẹ̀, sìmẹ́ntì, òkúta, páànù ìṣó àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.

Ilé ma ń ga bí ó bá ṣe wu onílé kí ilé òun ṣe ga sí, ilé gbọ́dọ̀ ní fèrèsé, ẹnu ọ̀nà àbáwọlé, iyàrá ksn tàbí púpọ̀, balùwẹ̀, ilé ìdáná, ilé ìgbọ̀sẹ̀ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ .[2][3]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "house". definition in the Cambridge English Dictionary. 2014-09-27. Retrieved 2023-02-02. 
  2. Schoenauer, Norbert (2000). 6,000 Years of Housing (rev. ed.) (New York: W.W. Norton & Company).
  3. "housing papers" (PDF). clerk.house.gov. Retrieved December 18, 2012.