Ilé Ìfowópamọ́ Agbọ́nmágbẹ

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ilé Ìfowópamọ́ Agbọ́nmágbẹ jẹ́ Ilé Ìfowópamọ́ ìbílẹ̀ àkọ́kọ́ lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí Ìjọba Àpapọ̀ fún láṣẹ. Olóyè Mathew Adékọ̀yà Òkúpè Agbọ́nmágbẹ ni ó dá a sílẹ̀ lọ́dún 1945. Ilé Ìfowópamọ́ Agbọ́nmágbẹ ló wá di Wema Bank tí òde òní. [1] [2] [3] [4] [5]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Salako, Femi (2018-03-22). "Tribute to a doyen of patriotism – Daily Trust". Daily Trust. Archived from the original on 2018-03-22. Retrieved 2020-01-08. 
  2. "Our History". Wemabank. 2017-12-14. Retrieved 2020-01-08. 
  3. "Okupe faults Subomi Balogun’s claims of being first indigenous banker - Vanguard News". Vanguard News. 2018-01-13. Retrieved 2020-01-08. 
  4. "3PLR – AGBONMAGBE BANK LTD V. C.F.A.O. – Judgements". Judgements – Law Nigeria. 2018-06-13. Retrieved 2020-01-08. 
  5. "Indigenous Banks in Colonial Nigeria on JSTOR". JSTOR. Retrieved 2020-01-08.