Ilé Alámọ̀

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ịlé Alámọ̀.

Ilé alámọ̀ jẹ́ àwọn ilé tí wọ́n fi amọ̀ ( ìyẹn iyẹ̀pẹ̀ pupa) kọ́. Àwọn ibi tí wọn kò tí fi bẹ́ẹ̀ lajú ni a ti máa ń bá àwọn ilé tí wọ́n fi amọ̀ kọ́ wọ̀nyí pàdé, gẹ́gẹ́ bí i ilé tí wọ́n ń gbé.

Àwọn mìíràn ti ẹ̀ máa ń kọ́ ilé alámọ̀ ní ìlànà ìlàjú, tí ó tún rẹwà ju àwọn èyí tí a máa ń bá pàdé ní àwọn ìlú tí wọn kò tí lajú lọ[1].

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Mud housing is the key". Down To Earth. 1992-10-15. Retrieved 2022-05-21.